ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 20:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí ìránṣẹ́ rẹ,+ nítorí o ti bá ìránṣẹ́ rẹ dá májẹ̀mú níwájú Jèhófà.+ Àmọ́ tí mo bá jẹ̀bi,+ ìwọ fúnra rẹ ni kí o pa mí. Má wulẹ̀ fà mí lé bàbá rẹ lọ́wọ́.”

  • 1 Sámúẹ́lì 20:42
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Jónátánì sọ fún Dáfídì pé: “Máa lọ ní àlàáfíà, nítorí àwa méjèèjì ti fi orúkọ Jèhófà búra+ pé, ‘Kí Jèhófà wà láàárín èmi àti ìwọ àti láàárín àwọn ọmọ* mi àti àwọn ọmọ* rẹ títí láé.’”+

      Dáfídì bá dìde, ó sì lọ, Jónátánì wá pa dà sínú ìlú.

  • 1 Sámúẹ́lì 23:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Àwọn méjèèjì wá dá májẹ̀mú+ níwájú Jèhófà, Dáfídì dúró sí Hóréṣì, Jónátánì sì gba ilé rẹ̀ lọ.

  • 2 Sámúẹ́lì 9:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Nígbà náà, Dáfídì sọ pé: “Ṣé ẹnì kankan ṣì kù ní ilé Sọ́ọ̀lù tí mo lè fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí nítorí Jónátánì?”+

  • 2 Sámúẹ́lì 21:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àmọ́ ṣá, ọba ṣàánú Méfíbóṣétì+ ọmọ Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù nítorí ìbúra tó wáyé níwájú Jèhófà láàárín Dáfídì àti Jónátánì+ ọmọ Sọ́ọ̀lù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́