1 Sámúẹ́lì 21:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lọ́jọ́ yẹn, Dáfídì gbéra, ó tún bẹ̀rẹ̀ sí í sá lọ+ nítorí Sọ́ọ̀lù, níkẹyìn ó dé ọ̀dọ̀ Ákíṣì ọba Gátì.+ 1 Sámúẹ́lì 27:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ni Dáfídì àti ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin+ tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ bá gbéra, wọ́n sì lọ sọ́dọ̀ Ákíṣì+ ọmọ Máókì, ọba Gátì.
10 Lọ́jọ́ yẹn, Dáfídì gbéra, ó tún bẹ̀rẹ̀ sí í sá lọ+ nítorí Sọ́ọ̀lù, níkẹyìn ó dé ọ̀dọ̀ Ákíṣì ọba Gátì.+
2 Ni Dáfídì àti ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin+ tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ bá gbéra, wọ́n sì lọ sọ́dọ̀ Ákíṣì+ ọmọ Máókì, ọba Gátì.