9 Gbogbo èyí ni a fi òkúta olówó ńlá ṣe,+ tí a sì gbẹ́ bó ṣe wà nínú ìwọ̀n, tí a fi ayùn òkúta rẹ́ nínú àti lóde, láti ìpìlẹ̀ títí dé ìbòrí ògiri àti lóde títí dé àgbàlá ńlá.+
2 Dáfídì wá pàṣẹ pé kí wọ́n kó àwọn àjèjì+ tó wà ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì jọ, ó sì yàn wọ́n ṣe agbẹ́kùúta láti máa gé òkúta, kí wọ́n sì máa gbẹ́ òkúta tí wọ́n á fi kọ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́.+