1 Àwọn Ọba 5:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọba pàṣẹ pé kí wọ́n fọ́ àwọn òkúta ńláńlá, àwọn òkúta iyebíye,+ kí wọ́n lè fi òkúta tí wọ́n bá gbẹ́+ ṣe ìpìlẹ̀ ilé+ náà.
17 Ọba pàṣẹ pé kí wọ́n fọ́ àwọn òkúta ńláńlá, àwọn òkúta iyebíye,+ kí wọ́n lè fi òkúta tí wọ́n bá gbẹ́+ ṣe ìpìlẹ̀ ilé+ náà.