-
1 Àwọn Ọba 7:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Ó fín àwọn kérúbù, kìnnìún àti igi ọ̀pẹ sára àwọn férémù kéékèèké àti sára àwọn iṣẹ́ ọnà pẹlẹbẹ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ bí àyè tó wà lára ọ̀kọ̀ọ̀kan ṣe fẹ̀ tó, ó sì ṣe ohun ọ̀ṣọ́ tó so kọ́ra yí i ká.+
-