ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 4:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Ó ṣe èyí, kí gbogbo aráyé lè mọ bí ọwọ́ Jèhófà ṣe lágbára tó,+ kí ẹ sì lè máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run yín nígbà gbogbo.’”

  • 1 Sámúẹ́lì 17:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Lónìí yìí, Jèhófà yóò fi ọ́ lé mi lọ́wọ́,+ màá mú ọ balẹ̀, màá sì gé orí rẹ kúrò. Lónìí yìí kan náà, màá fi òkú àwọn tó wà ní ibùdó àwọn Filísínì fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ẹran inú igbó; gbogbo àwọn èèyàn tó wà láyé yóò sì mọ̀ pé Ọlọ́run kan wà ní Ísírẹ́lì.+

  • Ìsíkíẹ́lì 36:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 ‘Ó dájú pé màá sọ orúkọ ńlá mi di mímọ́,+ èyí tí wọ́n kó ẹ̀gàn bá láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, tí ẹ kẹ́gàn rẹ̀ láàárín wọn; àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘nígbà tí mo bá fi hàn lójú wọn pé mo jẹ́ mímọ́ láàárín yín.

  • Ìsíkíẹ́lì 39:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Màá mú kí àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì mọ orúkọ mímọ́ mi, mi ò sì tún ní jẹ́ kí wọ́n kó ẹ̀gàn bá orúkọ mímọ́ mi mọ́; àwọn orílẹ̀-èdè á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,+ Ẹni Mímọ́ ní Ísírẹ́lì.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́