2 Kíróníkà 36:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sun ilé Ọlọ́run tòótọ́ kanlẹ̀,+ ó wó ògiri Jerúsálẹ́mù lulẹ̀,+ ó sun gbogbo àwọn ilé gogoro tó láàbò, ó sì ba gbogbo ohun tó ṣeyebíye jẹ́.+ Àìsáyà 64:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ilé* wa mímọ́ àti ológo,*Tí àwọn baba ńlá wa ti yìn ọ́,Ni wọ́n ti dáná sun,+Gbogbo àwọn ohun tó ṣeyebíye sí wa sì ti pa run.
19 Ó sun ilé Ọlọ́run tòótọ́ kanlẹ̀,+ ó wó ògiri Jerúsálẹ́mù lulẹ̀,+ ó sun gbogbo àwọn ilé gogoro tó láàbò, ó sì ba gbogbo ohun tó ṣeyebíye jẹ́.+
11 Ilé* wa mímọ́ àti ológo,*Tí àwọn baba ńlá wa ti yìn ọ́,Ni wọ́n ti dáná sun,+Gbogbo àwọn ohun tó ṣeyebíye sí wa sì ti pa run.