ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 11:12, 13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Àmọ́, nítorí Dáfídì bàbá rẹ, mi ò ní ṣe èyí nígbà ayé rẹ. Ọwọ́ ọmọ rẹ ni màá ti fà á ya,+ 13 àmọ́ kì í ṣe gbogbo ìjọba náà+ ni màá fà ya. Màá fún ọmọ rẹ ní ẹ̀yà kan,+ nítorí Dáfídì ìránṣẹ́ mi àti nítorí Jerúsálẹ́mù tí mo yàn.”+

  • 2 Kíróníkà 11:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì tó wà ní gbogbo Ísírẹ́lì dúró tì í, wọ́n ń jáde wá láti gbogbo ìpínlẹ̀ wọn.

  • 2 Kíróníkà 11:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àwọn tó wá láti gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì tí wọ́n ti pinnu láti máa wá Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì tẹ̀ lé àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì wá sí Jerúsálẹ́mù láti rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́