1 Àwọn Ọba 11:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́, nítorí Dáfídì bàbá rẹ, mi ò ní ṣe èyí nígbà ayé rẹ. Ọwọ́ ọmọ rẹ ni màá ti fà á ya,+ 13 àmọ́ kì í ṣe gbogbo ìjọba náà+ ni màá fà ya. Màá fún ọmọ rẹ ní ẹ̀yà kan,+ nítorí Dáfídì ìránṣẹ́ mi àti nítorí Jerúsálẹ́mù tí mo yàn.”+ Hósíà 11:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Irọ́ ni Éfúrémù ń pa fún mi ṣáá,Ẹ̀tàn sì ni ilé Ísírẹ́lì ń ṣe sí mi nígbà gbogbo.+ Àmọ́ Júdà ṣì ń bá Ọlọ́run rìn,Ó sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ẹni Mímọ́ Jù Lọ.”+
12 Àmọ́, nítorí Dáfídì bàbá rẹ, mi ò ní ṣe èyí nígbà ayé rẹ. Ọwọ́ ọmọ rẹ ni màá ti fà á ya,+ 13 àmọ́ kì í ṣe gbogbo ìjọba náà+ ni màá fà ya. Màá fún ọmọ rẹ ní ẹ̀yà kan,+ nítorí Dáfídì ìránṣẹ́ mi àti nítorí Jerúsálẹ́mù tí mo yàn.”+
12 “Irọ́ ni Éfúrémù ń pa fún mi ṣáá,Ẹ̀tàn sì ni ilé Ísírẹ́lì ń ṣe sí mi nígbà gbogbo.+ Àmọ́ Júdà ṣì ń bá Ọlọ́run rìn,Ó sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ẹni Mímọ́ Jù Lọ.”+