1 Àwọn Ọba 11:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Màá fún ọmọ rẹ̀ ní ẹ̀yà kan ṣoṣo, kí Dáfídì ìránṣẹ́ mi lè máa ṣàkóso* níwájú mi nígbà gbogbo ní Jerúsálẹ́mù,+ ìlú tí mo yàn fún ara mi láti fi orúkọ mi sí. 2 Kíróníkà 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ Jèhófà ò fẹ́ pa ilé Dáfídì run, nítorí májẹ̀mú tó bá Dáfídì dá,+ torí ó ti ṣèlérí pé Dáfídì àti àwọn ọmọ rẹ̀ lá máa ṣàkóso* títí lọ.+ Sáàmù 132:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Jèhófà ti yan Síónì;+Ó fẹ́ kó jẹ́ ibùgbé rẹ̀, ó ní:+ Sáàmù 132:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá mú kí agbára Dáfídì pọ̀ sí i* níbẹ̀. Mo ti ṣètò fìtílà fún ẹni àmì òróró mi.+
36 Màá fún ọmọ rẹ̀ ní ẹ̀yà kan ṣoṣo, kí Dáfídì ìránṣẹ́ mi lè máa ṣàkóso* níwájú mi nígbà gbogbo ní Jerúsálẹ́mù,+ ìlú tí mo yàn fún ara mi láti fi orúkọ mi sí.
7 Àmọ́ Jèhófà ò fẹ́ pa ilé Dáfídì run, nítorí májẹ̀mú tó bá Dáfídì dá,+ torí ó ti ṣèlérí pé Dáfídì àti àwọn ọmọ rẹ̀ lá máa ṣàkóso* títí lọ.+