ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 20:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Nígbà náà, Bẹni-hádádì+ ọba Síríà+ kó gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ àti àwọn ọba méjìlélọ́gbọ̀n (32) pẹ̀lú àwọn ẹṣin àti àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin wọn; ó jáde lọ, ó dó ti+ Samáríà,+ ó sì gbéjà kò ó.

  • 2 Àwọn Ọba 17:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Lẹ́yìn náà, ọba Ásíríà kó àwọn èèyàn wá láti Bábílónì, Kútà, Áfà, Hámátì àti Séfáfáímù,+ ó sì ní kí wọ́n máa gbé inú àwọn ìlú Samáríà níbi tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé tẹ́lẹ̀; wọ́n gba Samáríà, wọ́n sì ń gbé inú àwọn ìlú rẹ̀.

  • Émọ́sì 6:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Àwọn tó dá ara wọn lójú* ní Síónì gbé!

      Àwọn tí ọkàn wọn balẹ̀ lórí òkè Samáríà,+

      Àwọn olókìkí èèyàn nínú àwọn orílẹ̀-èdè tó gba iwájú,

      Àwọn tí ilé Ísírẹ́lì ń lọ sọ́dọ̀ wọn!

  • Ìṣe 8:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Lásìkò yìí, Fílípì lọ sí ìlú* Samáríà,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù nípa Kristi fún wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́