2 Àwọn Ọba 8:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Èlíṣà wá sí Damásíkù+ nígbà tí Bẹni-hádádì+ ọba Síríà ń ṣàìsàn. Torí náà, wọ́n ròyìn fún ọba pé: “Èèyàn Ọlọ́run tòótọ́+ ti dé síbí o.”
7 Èlíṣà wá sí Damásíkù+ nígbà tí Bẹni-hádádì+ ọba Síríà ń ṣàìsàn. Torí náà, wọ́n ròyìn fún ọba pé: “Èèyàn Ọlọ́run tòótọ́+ ti dé síbí o.”