ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 18:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 nígbà tí Jésíbẹ́lì+ ń pa àwọn wòlíì Jèhófà,* Ọbadáyà kó ọgọ́rùn-ún [100] wòlíì, ó fi wọ́n pa mọ́ ní àádọ́ta-àádọ́ta sínú ihò, ó sì ń fún wọn ní oúnjẹ àti omi.)

  • 1 Àwọn Ọba 18:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ní báyìí, pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ sọ́dọ̀ mi lórí Òkè Kámẹ́lì+ àti ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé àádọ́ta (450) wòlíì Báálì àti ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) wòlíì òpó òrìṣà,*+ tó ń jẹun lórí tábìlì Jésíbẹ́lì.”

  • 1 Àwọn Ọba 21:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Jésíbẹ́lì ìyàwó rẹ̀ sọ fún un pé: “Ìwọ kọ́ lò ń ṣàkóso lórí Ísírẹ́lì ni? Dìde, jẹun, kí o sì jẹ́ kí inú rẹ dùn. Màá fún ọ ní ọgbà àjàrà Nábótì ará Jésírẹ́lì.”+

  • 2 Àwọn Ọba 9:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Nígbà tí Jéhù dé Jésírẹ́lì,+ Jésíbẹ́lì+ gbọ́ pé ó ti dé. Torí náà, ó lé tìróò* sójú, ó ṣe irun rẹ̀ lóge, ó sì bojú wolẹ̀ látojú fèrèsé.*

  • Ìfihàn 2:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “‘Síbẹ̀, àwọn ohun kan wà tí mo rí tí ò ń ṣe tí kò dáa, o fàyè gba Jésíbẹ́lì+ obìnrin yẹn, ẹni tó pe ara rẹ̀ ní wòlíì obìnrin, tó ń kọ́ àwọn ẹrú mi, tó sì ń ṣì wọ́n lọ́nà kí wọ́n lè ṣe ìṣekúṣe,*+ kí wọ́n sì jẹ àwọn nǹkan tí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́