ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 14:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nígbà náà, jìnnìjìnnì bá àwọn tó wà ní ibùdó inú pápá àti gbogbo àwọn tó wà lára àwùjọ ọmọ ogun tó wà ní àdádó, ẹ̀rù sì ba agbo ọmọ ogun akónilẹ́rù.+ Ilẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í mì tìtì, Ọlọ́run sì mú kí jìnnìjìnnì bá wọn.

  • Jóòbù 9:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ó ń mi ayé tìtì kúrò ní àyè rẹ̀,

      Débi pé àwọn òpó rẹ̀ ń gbọ̀n rìrì.+

  • Sáàmù 68:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ayé mì tìtì;+

      Ọ̀run rọ òjò* nítorí Ọlọ́run;

      Sínáì yìí mì tìtì nítorí Ọlọ́run, àní Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+

  • Náhúmù 1:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Àwọn òkè ńlá mì tìtì nítorí rẹ̀,

      Àwọn òkè kéékèèké sì yọ́.+

      Ayé á ru sókè nítorí ojú rẹ̀,

      Àti ilẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn tó ń gbé orí rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́