1 Àwọn Ọba 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nígbà náà, Bẹni-hádádì+ ọba Síríà+ kó gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ àti àwọn ọba méjìlélọ́gbọ̀n (32) pẹ̀lú àwọn ẹṣin àti àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin wọn; ó jáde lọ, ó dó ti+ Samáríà,+ ó sì gbéjà kò ó. 2 Àwọn Ọba 6:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Lẹ́yìn ìgbà náà, Bẹni-hádádì ọba Síríà kó gbogbo ọmọ ogun* rẹ̀ jọ, ó sì lọ dó ti Samáríà.+
20 Nígbà náà, Bẹni-hádádì+ ọba Síríà+ kó gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ àti àwọn ọba méjìlélọ́gbọ̀n (32) pẹ̀lú àwọn ẹṣin àti àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin wọn; ó jáde lọ, ó dó ti+ Samáríà,+ ó sì gbéjà kò ó.