-
1 Àwọn Ọba 20:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Wọ́n jáde lọ ní ọ̀sán gangan nígbà tí Bẹni-hádádì ti rọ ara rẹ̀ yó nínú àwọn àgọ́* pẹ̀lú àwọn ọba méjìlélọ́gbọ̀n (32) tó ń ràn án lọ́wọ́.
-