2 Àwọn Ọba 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́, áńgẹ́lì Jèhófà sọ fún Èlíjà*+ ará Tíṣíbè pé: “Gbéra, lọ pàdé àwọn òjíṣẹ́ ọba Samáríà, kí o sọ fún wọn pé, ‘Ṣé kò sí Ọlọ́run ní Ísírẹ́lì ni, tí ẹ fi ń lọ wádìí lọ́dọ̀ Baali-sébúbù ọlọ́run Ẹ́kírónì?+
3 Àmọ́, áńgẹ́lì Jèhófà sọ fún Èlíjà*+ ará Tíṣíbè pé: “Gbéra, lọ pàdé àwọn òjíṣẹ́ ọba Samáríà, kí o sọ fún wọn pé, ‘Ṣé kò sí Ọlọ́run ní Ísírẹ́lì ni, tí ẹ fi ń lọ wádìí lọ́dọ̀ Baali-sébúbù ọlọ́run Ẹ́kírónì?+