36 Ní déédéé àkókò tí wọ́n máa ń fi ọrẹ ọkà ìrọ̀lẹ́ rúbọ,+ wòlíì Èlíjà wá síwájú, ó sì sọ pé: “Jèhófà, Ọlọ́run Ábúráhámù,+ Ísákì+ àti Ísírẹ́lì, jẹ́ kí wọ́n mọ̀ lónìí pé ìwọ ni Ọlọ́run Ísírẹ́lì àti pé ìránṣẹ́ rẹ ni mí, kí wọ́n sì mọ̀ pé ìwọ lo ní kí n ṣe gbogbo nǹkan yìí.+