ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 20:8-11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Hẹsikáyà ti béèrè lọ́wọ́ Àìsáyà pé: “Àmì+ wo ló máa jẹ́ kó dá mi lójú pé Jèhófà máa mú mi lára dá àti pé màá lè lọ sí ilé Jèhófà ní ọjọ́ kẹta?” 9 Àìsáyà fèsì pé: “Àmì tí Jèhófà fún ọ nìyí láti mú un dá ọ lọ́jú pé Jèhófà máa mú ọ̀rọ̀ tó sọ ṣẹ: Ṣé o fẹ́ kí òjìji tó wà lórí àtẹ̀gùn* lọ síwájú ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá tàbí kó pa dà sẹ́yìn ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá?”+ 10 Hẹsikáyà sọ pé: “Ó rọrùn fún òjìji láti lọ síwájú ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá, àmọ́ kì í ṣe bíi pé kò pa dà sẹ́yìn ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá.” 11 Torí náà, wòlíì Àìsáyà ké pe Jèhófà, Ó sì mú kí òjìji tó wà lórí àtẹ̀gùn Áhásì pa dà sẹ́yìn ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá lẹ́yìn tó ti kọ́kọ́ lọ síwájú lórí àtẹ̀gùn náà.+

  • Àìsáyà 38:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Màá mú kí òjìji oòrùn tó ń sọ̀ kalẹ̀ lórí àtẹ̀gùn* Áhásì pa dà sẹ́yìn ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá.”’”+ Oòrùn wá pa dà sẹ́yìn ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá lẹ́yìn tó ti kọ́kọ́ lọ síwájú lórí àtẹ̀gùn náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́