Diutarónómì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Máa rántí ọ̀nà jíjìn tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ mú ọ rìn ní aginjù fún ogójì (40) ọdún yìí,+ kó lè rẹ̀ ọ́ sílẹ̀, kó sì dán ọ wò,+ kó lè mọ ohun tó wà lọ́kàn rẹ,+ bóyá wàá pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ tàbí o ò ní pa wọ́n mọ́. Sáàmù 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jọ̀wọ́, fòpin sí ìwà ibi àwọn ẹni burúkú. Àmọ́, fìdí olódodo múlẹ̀,+Nítorí pé Ọlọ́run olódodo ni ọ́,+ tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn+ àti inú lọ́hùn-ún.*+ Sáàmù 139:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Yẹ̀ mí wò látòkè délẹ̀, Ọlọ́run, kí o sì mọ ọkàn mi.+ Ṣàyẹ̀wò mi, kí o sì mọ àwọn ohun tó ń gbé mi lọ́kàn sókè.*+
2 Máa rántí ọ̀nà jíjìn tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ mú ọ rìn ní aginjù fún ogójì (40) ọdún yìí,+ kó lè rẹ̀ ọ́ sílẹ̀, kó sì dán ọ wò,+ kó lè mọ ohun tó wà lọ́kàn rẹ,+ bóyá wàá pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ tàbí o ò ní pa wọ́n mọ́.
9 Jọ̀wọ́, fòpin sí ìwà ibi àwọn ẹni burúkú. Àmọ́, fìdí olódodo múlẹ̀,+Nítorí pé Ọlọ́run olódodo ni ọ́,+ tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn+ àti inú lọ́hùn-ún.*+
23 Yẹ̀ mí wò látòkè délẹ̀, Ọlọ́run, kí o sì mọ ọkàn mi.+ Ṣàyẹ̀wò mi, kí o sì mọ àwọn ohun tó ń gbé mi lọ́kàn sókè.*+