ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 30:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Hẹsikáyà ránṣẹ́ sí gbogbo Ísírẹ́lì+ àti Júdà, ó tiẹ̀ tún kọ lẹ́tà sí Éfúrémù àti Mánásè,+ pé kí wọ́n wá sí ilé Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù láti wá ṣe Ìrékọjá sí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+

  • 2 Kíróníkà 30:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Bákan náà, ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́ wà ní Júdà láti mú wọn ṣọ̀kan* kí wọ́n lè ṣe ohun tí ọba àti àwọn ìjòyè pa láṣẹ, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Jèhófà.

  • 2 Kíróníkà 33:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Ọmọ ọdún méjìlá (12) ni Mánásè+ nígbà tó jọba, ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+

  • 2 Kíróníkà 33:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ó tún ṣètò pẹpẹ Jèhófà,+ ó bẹ̀rẹ̀ sí í rú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ àti àwọn ẹbọ ìdúpẹ́+ lórí rẹ̀, ó sì sọ fún Júdà pé kí wọ́n máa sin Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́