-
Jeremáyà 26:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Ọkùnrin kan tún wà tó ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ ní orúkọ Jèhófà, Úríjà ọmọ Ṣemáyà láti Kiriati-jéárímù,+ tí ọ̀rọ̀ tó sọ tẹ́lẹ̀ nípa ìlú yìí àti ilẹ̀ yìí dà bíi ti Jeremáyà. 21 Ọba Jèhóákímù+ àti gbogbo àwọn ọkùnrin rẹ̀ alágbára àti gbogbo ìjòyè sì gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, ọba sì wá ọ̀nà láti pa á.+ Nígbà tí Úríjà gbọ́ nípa rẹ̀, lójú ẹsẹ̀, ẹ̀rù bà á, ó sì sá lọ sí Íjíbítì.
-