Jeremáyà 36:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mú àkájọ ìwé kan, kí o sì kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo bá ọ sọ sínú rẹ̀, ọ̀rọ̀ tí mo sọ sí Ísírẹ́lì àti Júdà+ àti gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè,+ láti ọjọ́ tí mo kọ́kọ́ bá ọ sọ̀rọ̀ nígbà ayé Jòsáyà, títí di òní yìí.+ Jeremáyà 36:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jeremáyà bá pe Bárúkù+ ọmọ Neráyà, Jeremáyà sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jèhófà ti bá a sọ, Bárúkù sì ń kọ ọ́ sínú àkájọ ìwé náà.+
2 “Mú àkájọ ìwé kan, kí o sì kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo bá ọ sọ sínú rẹ̀, ọ̀rọ̀ tí mo sọ sí Ísírẹ́lì àti Júdà+ àti gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè,+ láti ọjọ́ tí mo kọ́kọ́ bá ọ sọ̀rọ̀ nígbà ayé Jòsáyà, títí di òní yìí.+
4 Jeremáyà bá pe Bárúkù+ ọmọ Neráyà, Jeremáyà sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jèhófà ti bá a sọ, Bárúkù sì ń kọ ọ́ sínú àkájọ ìwé náà.+