-
1 Àwọn Ọba 4:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Àwọn èèyàn ń wá láti gbogbo orílẹ̀-èdè kí wọ́n lè gbọ́ ọgbọ́n Sólómọ́nì, títí kan àwọn ọba láti ibi gbogbo láyé tí wọ́n ti gbọ́ nípa ọgbọ́n rẹ̀.+
-
-
2 Kíróníkà 1:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 màá fún ọ ní ọgbọ́n àti ìmọ̀; màá tún fún ọ ní ọlá àti ọrọ̀ àti iyì irú èyí tí àwọn ọba tó ṣáájú rẹ kò ní, kò sì ní sí èyí tó máa ní irú rẹ̀ lẹ́yìn rẹ.”+
-