1 Àwọn Ọba 8:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Àmọ́, ṣé Ọlọ́run máa gbé inú ayé ni?+ Wò ó! Àwọn ọ̀run, àní, ọ̀run àwọn ọ̀run, kò lè gbà ọ́;+ ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti ilé tí mo kọ́ yìí!+ Àìsáyà 66:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 66 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé sì ni àpótí ìtìsẹ̀ mi.+ Ilé wo wá ni ẹ lè kọ́ fún mi,+Ibo sì ni ibi ìsinmi mi?”+ Ìṣe 17:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọlọ́run tó dá ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí òun fúnra rẹ̀ ṣe jẹ́ Olúwa ọ̀run àti ayé,+ kì í gbé inú àwọn tẹ́ńpìlì tí a fi ọwọ́ kọ́;+
27 “Àmọ́, ṣé Ọlọ́run máa gbé inú ayé ni?+ Wò ó! Àwọn ọ̀run, àní, ọ̀run àwọn ọ̀run, kò lè gbà ọ́;+ ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti ilé tí mo kọ́ yìí!+
66 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé sì ni àpótí ìtìsẹ̀ mi.+ Ilé wo wá ni ẹ lè kọ́ fún mi,+Ibo sì ni ibi ìsinmi mi?”+
24 Ọlọ́run tó dá ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí òun fúnra rẹ̀ ṣe jẹ́ Olúwa ọ̀run àti ayé,+ kì í gbé inú àwọn tẹ́ńpìlì tí a fi ọwọ́ kọ́;+