-
1 Àwọn Ọba 15:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ó kó àwọn ohun tí òun àti bàbá rẹ̀ ti yà sí mímọ́ wá sínú ilé Jèhófà, ìyẹn fàdákà, wúrà àti àwọn ohun èlò míì.+