ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 14:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù.+ Ẹ dúró gbọn-in, kí ẹ sì rí bí Jèhófà ṣe máa gbà yín là lónìí.+ Torí àwọn ará Íjíbítì tí ẹ rí lónìí yìí, ẹ ò ní rí wọn mọ́ láé.+ 14 Jèhófà fúnra rẹ̀ máa jà fún yín,+ ẹ ó sì dákẹ́ jẹ́ẹ́.”

  • Ẹ́kísódù 15:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+

      Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+

  • 1 Sámúẹ́lì 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Nígbà náà, Hánà gbàdúrà pé:

      “Ọkàn mi yọ̀ nínú Jèhófà;+

      Jèhófà ti fún mi lágbára.*

      Ẹnu mi gbọ̀rọ̀ lójú àwọn ọ̀tá mi,

      Nítorí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ ń mú inú mi dùn.

  • 1 Kíróníkà 16:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ẹ kọrin sí Jèhófà, gbogbo ayé!

      Ẹ kéde ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́!+

  • Ìdárò 3:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ó dáa kí èèyàn dúró jẹ́ẹ́*+ de ìgbàlà Jèhófà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́