ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 24:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé* Sekaráyà ọmọ àlùfáà Jèhóádà,+ ó dúró sórí ibi tó ga láàárín àwọn èèyàn náà, ó sì sọ fún wọn pé: “Ohun tí Ọlọ́run tòótọ́ sọ nìyí, ‘Kí ló dé tí ẹ fi ń tẹ àwọn àṣẹ Jèhófà lójú? Ẹ ò ní ṣàṣeyọrí! Nítorí ẹ ti fi Jèhófà sílẹ̀, òun náà á sì fi yín sílẹ̀.’”+

  • Sáàmù 115:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Àwọn tó ń ṣe wọ́n yóò dà bíi wọn gẹ́lẹ́,+

      Bẹ́ẹ̀ ló sì ṣe máa rí fún gbogbo àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé wọn.+

  • Jeremáyà 2:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

      “Ẹ̀sùn wo ni àwọn baba ńlá yín fi kàn mí,+

      Tí wọ́n fi lọ jìnnà kúrò lọ́dọ̀ mi,

      Tí wọ́n ń sin àwọn òrìṣà asán,+ tí àwọn fúnra wọn sì di asán?+

  • Jeremáyà 10:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Wọ́n dà bí aṣọ́komásùn tó wà nínú oko kùkúńbà,* wọn ò lè sọ̀rọ̀;+

      Ńṣe là ń gbé wọn, torí wọn ò lè rìn.+

      Má bẹ̀rù wọn, torí wọn ò lè pani lára,

      Bẹ́ẹ̀ ni wọn ò lè ṣeni lóore kankan.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́