17 Lákòókò yẹn, àwọn èèyàn pàtàkì+ ní Júdà ń fi ọ̀pọ̀ lẹ́tà ránṣẹ́ sí Tòbáyà, Tòbáyà sì ń dá èsì pa dà. 18 Ọ̀pọ̀ àwọn tó wà ní Júdà búra pé ẹ̀yìn rẹ̀ làwọn wà, torí pé ó jẹ́ àna Ṣẹkanáyà ọmọ Áráhì,+ Jèhóhánánì ọmọ rẹ̀ sì fẹ́ ọmọbìnrin Méṣúlámù+ ọmọ Berekáyà.