Sáàmù 103:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Aláàánú ni Jèhófà, ó sì ń gba tẹni rò,*+Kì í tètè bínú, ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀* sì pọ̀ gidigidi.+ Sáàmù 103:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kò fi àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa hùwà sí wa,+Kò sì fi ìyà tó yẹ àṣìṣe wa jẹ wá.+ Ìdárò 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ ni ò jẹ́ ká ṣègbé,+Nítorí àánú rẹ̀ kò ní dópin láé.+