-
Nehemáyà 7:57-60Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
57 Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì nìyí:+ àwọn ọmọ Sótáì, àwọn ọmọ Sóférétì, àwọn ọmọ Pérídà, 58 àwọn ọmọ Jáálà, àwọn ọmọ Dákónì, àwọn ọmọ Gídélì, 59 àwọn ọmọ Ṣẹfatáyà, àwọn ọmọ Hátílì, àwọn ọmọ Pokereti-hásébáímù, àwọn ọmọ Ámọ́nì. 60 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ àti ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ó lé àádọ́rùn-ún àti méjì (392).
-