-
Ẹ́sírà 2:55-58Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
55 Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì nìyí: àwọn ọmọ Sótáì, àwọn ọmọ Sóférétì, àwọn ọmọ Pérúdà,+ 56 àwọn ọmọ Jálà, àwọn ọmọ Dákónì, àwọn ọmọ Gídélì, 57 àwọn ọmọ Ṣẹfatáyà, àwọn ọmọ Hátílì, àwọn ọmọ Pokereti-hásébáímù àti àwọn ọmọ Ámì.
58 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* àti ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ó lé àádọ́rùn-ún àti méjì (392).
-