Jóṣúà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn tó ń gbé Gíbíónì+ náà gbọ́ ohun tí Jóṣúà ṣe sí Jẹ́ríkò+ àti Áì.+ Jóṣúà 9:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àmọ́ ọjọ́ yẹn ni Jóṣúà sọ wọ́n di aṣẹ́gi àti àwọn tí á máa pọnmi fún àpéjọ náà+ àti pẹpẹ Jèhófà ní ibi tí Ó bá yàn,+ iṣẹ́ tí wọ́n sì ń ṣe títí di òní nìyẹn.+ Nehemáyà 3:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà.
27 Àmọ́ ọjọ́ yẹn ni Jóṣúà sọ wọ́n di aṣẹ́gi àti àwọn tí á máa pọnmi fún àpéjọ náà+ àti pẹpẹ Jèhófà ní ibi tí Ó bá yàn,+ iṣẹ́ tí wọ́n sì ń ṣe títí di òní nìyẹn.+
26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà.