Diutarónómì 1:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Jèhófà Ọlọ́run yín máa lọ níwájú yín, ó sì máa jà fún yín,+ bó ṣe jà fún yín ní Íjíbítì tí ẹ̀yin náà sì fi ojú ara yín rí i.+ Jóṣúà 23:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹnì kan péré nínú yín máa lé ẹgbẹ̀rún (1,000),+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ń jà fún yín+ bó ṣe ṣèlérí fún yín.+
30 Jèhófà Ọlọ́run yín máa lọ níwájú yín, ó sì máa jà fún yín,+ bó ṣe jà fún yín ní Íjíbítì tí ẹ̀yin náà sì fi ojú ara yín rí i.+
10 Ẹnì kan péré nínú yín máa lé ẹgbẹ̀rún (1,000),+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ń jà fún yín+ bó ṣe ṣèlérí fún yín.+