Nehemáyà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní oṣù Nísàn,* ní ogún ọdún + Ọba Atasásítà,+ wáìnì wà níwájú ọba, mo gbé wáìnì bí mo ti máa ń ṣe, mo sì gbé e fún ọba.+ Àmọ́ mi ò fajú ro níwájú rẹ̀ rí.
2 Ní oṣù Nísàn,* ní ogún ọdún + Ọba Atasásítà,+ wáìnì wà níwájú ọba, mo gbé wáìnì bí mo ti máa ń ṣe, mo sì gbé e fún ọba.+ Àmọ́ mi ò fajú ro níwájú rẹ̀ rí.