Nehemáyà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Élíáṣíbù+ àlùfáà àgbà àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn àlùfáà, dìde láti kọ́ Ẹnubodè Àgùntàn.+ Wọ́n yà á sí mímọ́,+ wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró; wọ́n yà á sí mímọ́ títí dé Ilé Gogoro Méà+ àti títí dé Ilé Gogoro Hánánélì.+ Nehemáyà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ Hásénà mọ Ẹnubodè Ẹja;+ wọ́n fi ẹ̀là gẹdú kọ́ ọ,+ lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ sí i àti àwọn ìkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.
3 Élíáṣíbù+ àlùfáà àgbà àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn àlùfáà, dìde láti kọ́ Ẹnubodè Àgùntàn.+ Wọ́n yà á sí mímọ́,+ wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró; wọ́n yà á sí mímọ́ títí dé Ilé Gogoro Méà+ àti títí dé Ilé Gogoro Hánánélì.+
3 Àwọn ọmọ Hásénà mọ Ẹnubodè Ẹja;+ wọ́n fi ẹ̀là gẹdú kọ́ ọ,+ lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ sí i àti àwọn ìkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.