Ẹ́sírà 2:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Àwọn ọmọ àwọn aṣọ́bodè nìyí:+ àwọn ọmọ Ṣálúmù, àwọn ọmọ Átérì, àwọn ọmọ Tálímónì,+ àwọn ọmọ Ákúbù,+ àwọn ọmọ Hátítà, àwọn ọmọ Ṣóbáì, gbogbo wọn lápapọ̀ jẹ́ mọ́kàndínlógóje (139). Nehemáyà 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí a tún ògiri náà mọ tán,+ mo gbé àwọn ilẹ̀kùn sí i;+ lẹ́yìn náà, a yan àwọn aṣọ́bodè,+ àwọn akọrin+ àti àwọn ọmọ Léfì.+
42 Àwọn ọmọ àwọn aṣọ́bodè nìyí:+ àwọn ọmọ Ṣálúmù, àwọn ọmọ Átérì, àwọn ọmọ Tálímónì,+ àwọn ọmọ Ákúbù,+ àwọn ọmọ Hátítà, àwọn ọmọ Ṣóbáì, gbogbo wọn lápapọ̀ jẹ́ mọ́kàndínlógóje (139).
7 Nígbà tí a tún ògiri náà mọ tán,+ mo gbé àwọn ilẹ̀kùn sí i;+ lẹ́yìn náà, a yan àwọn aṣọ́bodè,+ àwọn akọrin+ àti àwọn ọmọ Léfì.+