Ìdárò 4:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wòlíì rẹ̀ àti àṣìṣe àwọn àlùfáà rẹ̀,+Tí wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ àwọn olódodo sílẹ̀ láàárín rẹ̀.+ נ [Núnì] 14 Wọ́n ti rìn kiri bí afọ́jú+ ní àwọn ojú ọ̀nà. Ẹ̀jẹ̀ ti sọ wọ́n di aláìmọ́,+Tí kò fi sí ẹnikẹ́ni tó lè fọwọ́ kan ẹ̀wù wọn.
13 Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wòlíì rẹ̀ àti àṣìṣe àwọn àlùfáà rẹ̀,+Tí wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ àwọn olódodo sílẹ̀ láàárín rẹ̀.+ נ [Núnì] 14 Wọ́n ti rìn kiri bí afọ́jú+ ní àwọn ojú ọ̀nà. Ẹ̀jẹ̀ ti sọ wọ́n di aláìmọ́,+Tí kò fi sí ẹnikẹ́ni tó lè fọwọ́ kan ẹ̀wù wọn.