-
Ẹ́sírà 8:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Mo wá pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n lọ bá Ídò tó jẹ́ olórí ní ibi tí wọ́n ń pè ní Kásífíà. Mo ní kí wọ́n sọ fún Ídò àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* tí wọ́n wà ní Kásífíà pé kí wọ́n bá wa mú àwọn òjíṣẹ́ wá fún ilé Ọlọ́run wa.
-