Nehemáyà 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn yìí ni àwọn èèyàn ìpínlẹ̀* tí wọ́n pa dà lára àwọn tó wà nígbèkùn, àwọn tí Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì kó lọ sí ìgbèkùn,+ àmọ́ tí wọ́n pa dà sí Jerúsálẹ́mù àti Júdà nígbà tó yá, kálukú pa dà sí ìlú rẹ̀,+ Nehemáyà 7:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Àwọn akọrin nìyí:+ àwọn ọmọ Ásáfù,+ wọ́n jẹ́ méjìdínláàádọ́jọ (148).
6 Àwọn yìí ni àwọn èèyàn ìpínlẹ̀* tí wọ́n pa dà lára àwọn tó wà nígbèkùn, àwọn tí Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì kó lọ sí ìgbèkùn,+ àmọ́ tí wọ́n pa dà sí Jerúsálẹ́mù àti Júdà nígbà tó yá, kálukú pa dà sí ìlú rẹ̀,+