-
1 Kíróníkà 2:54Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
54 Àwọn ọmọ Sálímà ni Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+ àwọn ará Nétófà, Atiroti-bẹti-jóábù, ìdajì àwọn ọmọ Mánáhátì àti àwọn Sórítì.
-
-
1 Kíróníkà 9:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ọbadáyà ọmọ Ṣemáyà ọmọ Gálálì ọmọ Jédútúnì àti Berekáyà ọmọ Ásà ọmọ Ẹlikénà, ẹni tó ń gbé ní ibi tí àwọn ará Nétófà+ tẹ̀ dó sí.
-
-
Nehemáyà 7:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 àwọn ọkùnrin Bẹ́tílẹ́hẹ́mù àti Nétófà jẹ́ ọgọ́sàn-án ó lé mẹ́jọ (188);
-