Jeremáyà 31:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Ní àkókò yẹn, wúńdíá á máa jó ijó ayọ̀,Àwọn ọ̀dọ́kùnrin àti àwọn àgbà ọkùnrin á máa jó pa pọ̀.+ Màá sọ ọ̀fọ̀ wọn di ìdùnnú.+ Màá tù wọ́n nínú, màá sì fún wọn ní ayọ̀ dípò ẹ̀dùn ọkàn tí wọ́n ní.+
13 “Ní àkókò yẹn, wúńdíá á máa jó ijó ayọ̀,Àwọn ọ̀dọ́kùnrin àti àwọn àgbà ọkùnrin á máa jó pa pọ̀.+ Màá sọ ọ̀fọ̀ wọn di ìdùnnú.+ Màá tù wọ́n nínú, màá sì fún wọn ní ayọ̀ dípò ẹ̀dùn ọkàn tí wọ́n ní.+