Nehemáyà 10:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Tí àwọn èèyàn ilẹ̀ náà bá kó ọjà tàbí oríṣiríṣi ọkà wá ní ọjọ́ Sábáàtì, a kò ní ra ohunkóhun lọ́wọ́ wọn ní Sábáàtì+ tàbí ní ọjọ́ mímọ́.+ A tún máa fi irè oko wa tó bá jáde ní ọdún keje+ sílẹ̀ àti gbogbo gbèsè tí ẹnikẹ́ni bá jẹ wá.+
31 Tí àwọn èèyàn ilẹ̀ náà bá kó ọjà tàbí oríṣiríṣi ọkà wá ní ọjọ́ Sábáàtì, a kò ní ra ohunkóhun lọ́wọ́ wọn ní Sábáàtì+ tàbí ní ọjọ́ mímọ́.+ A tún máa fi irè oko wa tó bá jáde ní ọdún keje+ sílẹ̀ àti gbogbo gbèsè tí ẹnikẹ́ni bá jẹ wá.+