Diutarónómì 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jèhófà máa tú yín ká sáàárín àwọn èèyàn,+ díẹ̀ nínú yín ló sì máa ṣẹ́ kù+ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà máa lé yín lọ. Nehemáyà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Jọ̀ọ́, rántí ọ̀rọ̀ tí o pa láṣẹ fún* Mósè ìránṣẹ́ rẹ pé: ‘Tí ẹ bá hùwà àìṣòótọ́, màá fọ́n yín ká sáàárín àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè.+ Jeremáyà 50:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Àwọn èèyàn Ísírẹ́lì jẹ́ àwọn àgùntàn tó tú ká.+ Àwọn kìnnìún ti fọ́n wọn ká.+ Ọba Ásíríà ló kọ́kọ́ jẹ wọ́n;+ lẹ́yìn náà, Nebukadinésárì* ọba Bábílónì jẹ egungun wọn.+
27 Jèhófà máa tú yín ká sáàárín àwọn èèyàn,+ díẹ̀ nínú yín ló sì máa ṣẹ́ kù+ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà máa lé yín lọ.
8 “Jọ̀ọ́, rántí ọ̀rọ̀ tí o pa láṣẹ fún* Mósè ìránṣẹ́ rẹ pé: ‘Tí ẹ bá hùwà àìṣòótọ́, màá fọ́n yín ká sáàárín àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè.+
17 “Àwọn èèyàn Ísírẹ́lì jẹ́ àwọn àgùntàn tó tú ká.+ Àwọn kìnnìún ti fọ́n wọn ká.+ Ọba Ásíríà ló kọ́kọ́ jẹ wọ́n;+ lẹ́yìn náà, Nebukadinésárì* ọba Bábílónì jẹ egungun wọn.+