- 
	                        
            
            Jóòbù 3:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Kí ló dé tí mi ò kú nígbà tí wọ́n bí mi? Kí ló dé tí mi ò ṣègbé nígbà tí mo jáde látinú ikùn?+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 20:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        18 Kí nìdí tí mo fi jáde kúrò nínú ikùn Láti rí ìdààmú àti ẹ̀dùn ọkàn, Láti mú kí àwọn ọjọ́ mi dópin nínú ìtìjú?+ 
 
-