-
Àìsáyà 32:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ófélì+ àti ilé ìṣọ́ ti di ahoro títí láé,
Ààyò àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó,
Ibi ìjẹko àwọn agbo ẹran,+
-
Jeremáyà 14:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó dúró lórí àwọn òkè.
-
-
-