Òwe 8:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà tó dá ọ̀run,+ mo wà níbẹ̀;Nígbà tó fi ààlà* sí orí omi,+ Jeremáyà 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 ‘Ṣé ẹ kò bẹ̀rù mi ni?’ ni Jèhófà wí,‘Ṣé kò yẹ kí ẹ̀rù bà yín níwájú mi? Èmi ni mo fi iyanrìn pààlà òkun,Ó jẹ́ ìlànà tó wà títí láé tí òkun kò lè ré kọjá. Bí àwọn ìgbì rẹ̀ tiẹ̀ ń bì síwá-sẹ́yìn, wọn kò lè borí;Bí wọ́n tiẹ̀ pariwo, síbẹ̀, wọn kò lè ré e kọjá.+
27 Nígbà tó dá ọ̀run,+ mo wà níbẹ̀;Nígbà tó fi ààlà* sí orí omi,+ Jeremáyà 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 ‘Ṣé ẹ kò bẹ̀rù mi ni?’ ni Jèhófà wí,‘Ṣé kò yẹ kí ẹ̀rù bà yín níwájú mi? Èmi ni mo fi iyanrìn pààlà òkun,Ó jẹ́ ìlànà tó wà títí láé tí òkun kò lè ré kọjá. Bí àwọn ìgbì rẹ̀ tiẹ̀ ń bì síwá-sẹ́yìn, wọn kò lè borí;Bí wọ́n tiẹ̀ pariwo, síbẹ̀, wọn kò lè ré e kọjá.+
22 ‘Ṣé ẹ kò bẹ̀rù mi ni?’ ni Jèhófà wí,‘Ṣé kò yẹ kí ẹ̀rù bà yín níwájú mi? Èmi ni mo fi iyanrìn pààlà òkun,Ó jẹ́ ìlànà tó wà títí láé tí òkun kò lè ré kọjá. Bí àwọn ìgbì rẹ̀ tiẹ̀ ń bì síwá-sẹ́yìn, wọn kò lè borí;Bí wọ́n tiẹ̀ pariwo, síbẹ̀, wọn kò lè ré e kọjá.+