Àìsáyà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó wá ku ọmọbìnrin Síónì nìkan, bí àtíbàbà nínú ọgbà àjàrà,Bí ahéré nínú oko kùkúńbà,*Bí ìlú tí wọ́n gbógun tì.+ Ìdárò 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó ṣe àtíbàbà rẹ̀ ṣúkaṣùka+ bí ahéré tó wà nínú oko. Ó ti fòpin sí* àjọyọ̀ rẹ̀.+ Jèhófà ti mú kí a gbàgbé àjọyọ̀ àti sábáàtì ní Síónì,Kò sì ka ọba àti àlùfáà sí nígbà tí inú ń bí i gan-an.+
8 Ó wá ku ọmọbìnrin Síónì nìkan, bí àtíbàbà nínú ọgbà àjàrà,Bí ahéré nínú oko kùkúńbà,*Bí ìlú tí wọ́n gbógun tì.+
6 Ó ṣe àtíbàbà rẹ̀ ṣúkaṣùka+ bí ahéré tó wà nínú oko. Ó ti fòpin sí* àjọyọ̀ rẹ̀.+ Jèhófà ti mú kí a gbàgbé àjọyọ̀ àti sábáàtì ní Síónì,Kò sì ka ọba àti àlùfáà sí nígbà tí inú ń bí i gan-an.+