Jóòbù 24:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ojú alágbèrè ń dúró de ìrọ̀lẹ́,+Ó ń sọ pé, ‘Kò sẹ́ni tó máa rí mi!’+ Ó sì ń bo ojú rẹ̀.