Òwe 15:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Jèhófà jìnnà réré sí àwọn ẹni burúkú,Àmọ́ ó máa ń gbọ́ àdúrà àwọn olódodo.+ Àìsáyà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+ Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+ Jeremáyà 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Wò ó, màá mú àjálù+ tí wọn kò ní lè bọ́ nínú rẹ̀ wá bá wọn. Nígbà tí wọ́n bá ké pè mí fún ìrànlọ́wọ́, mi ò ní fetí sí wọn.+
15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+ Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+
11 Torí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Wò ó, màá mú àjálù+ tí wọn kò ní lè bọ́ nínú rẹ̀ wá bá wọn. Nígbà tí wọ́n bá ké pè mí fún ìrànlọ́wọ́, mi ò ní fetí sí wọn.+